Home LÁGBO ÀRÍYÁ Ogoji odun lori itage: Dele Odule fe da ere onise pada
LÁGBO ÀRÍYÁ - April 26, 2017

Ogoji odun lori itage: Dele Odule fe da ere onise pada

Ohun kan pataki to je ogbontarigi osere, Alagba Dele Odule, logun bayii ni bi ere tiata onise ati alarinka yoo se pada si orile ede yii.
Nipa bee, Odule ti bere eto pataki kan nibi ti o ti n ko awon to ni ebun ere tiata jo, ti won si fe se ere pataki kan, OJU KELEKUN.
Kaakiri awon ile Yoruba ni o ti n fun awon eniyan laaye lati kopa ninu ere naa ati awon eyi ti yoo tun se leyin re.
Odule n se eyi lati se ayajo ogoji odun to ti wa ninu ise tiata.
O ni nnkan dara gidi late awon Ogunde ati Baba Sala, to si je pe anfaani nla lo wa ninu ere ori itage.
Odule tun n se eyi lati ran awon odo langba lowo, ko si mu itesiwaju ba ilu.
Osere naa ni owo bii milionu mewaa naira ni oun nilo lati se eto yii, ti oun si nigbagbo pe iranlowo yoo yo lati orisiirisii ona.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…