Home Orisirisi Olumide Bakare dara ile
Orisirisi - April 22, 2017

Olumide Bakare dara ile

Gbaju-gbaja osere ni Olumide Bakare, o kawe de Fasiti. O sise pelu ileeese telifison ijoba apapo NTA, oun ni Lanlord Oluwalambe lodge, koko close. Ere Landlord yii ni o tan imole si irawo re. Baba yii kopa pupo ninu ere ori itage, sinima, o fi igba kan wa pelu Wale Adenuga, ninu Super Stories ati bee bee lo.

Olumide Bakare pe ni ilu Ibadan gan-an, ki o ti di pe aisan okan bere si ni baa ja ni odun 2013 si 2014. UCH Ibadan ni won ti koko n toju re ki o to di wi pe omo re kan pelu aburo gbe lo fun itoju ni oke okun. Odun 2015 lo pada de si Naijiria.

Awon Dokita to n toju re figba kan kilo fun un ki o fi oti ati siga minu sile. Iku o ki n pani ki o ma se ka nnkan mo eni lowo. Egbe osere, ile Yoruba ati Naijiria lapapo padanu Olumide Bakare ni omo odun marundinlaadorin (65 years).

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…