Home ÀKỌ̀TUN Fúnkẹ́ Adésiyan rántí ọjọ́ tí Wasiu Ayinde fún un ní $5,000
ÀKỌ̀TUN - iroyin - LÁGBO ÀRÍYÁ - March 6, 2017

Fúnkẹ́ Adésiyan rántí ọjọ́ tí Wasiu Ayinde fún un ní $5,000

O ni, ‘Baba ni o je si mi’

Osere fiimu ti a mo si Funke Adesiyan ti so pe bii baba ni akorin fuji pataki, Wasiu Ayinde, je si oun.

O ni ti oun ba pe Kwam 1 ni ore oun nikan, oun kan n pala enu ni.

Funke so eyi nigba to n ki Wasiu ku oriire ojo ibi ogota odun to sese se.

Funke ranti ojo ti akorin fuji naa fun oun lowo ni ilu oyinbo, nigba ti oun n kawe nibe.

O ni lojo naa, o ya Wasiu lenu lati ri i pe owo to to egberun lona adoto dola o le die ($56,000) ni owo ti oun n san lati ran ara oun lo si ile iwe.

O ni ibe ni Wasiu ti fun oun ni egberun marun-un dola ($5000), lati ran oun lowo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…