Home iroyin Yegede, Adeboye pe eni odun marundinlogorin O so ohun to n dun un lokan
iroyin - February 19, 2017

Yegede, Adeboye pe eni odun marundinlogorin O so ohun to n dun un lokan

Opo eniyan lo si n ki Oluso Agba fun Gbogbo Agbaye ni ijo Redeemed Christian Curch of God, Ojise Olorun E.A. Adeboye, ku oriire nitori Olorun ti fi okan kun odun won.
Koda, orin olojo ibi emi re a se pupo, feso maa jo, ijo oni nnkan ni won n ko fun baba.
Baba Adeboye di eni odun marundinlogorin (75 years) lori ile alaaye.
Nipa bee, ljo ori, won kii se egbe awon gbajugbaja pasito miiran bii Tunde Bakare, TB Joshua, David Oyedepo ati Bishop Okonwo.
Sugbon bi inu baba naa se n dun sinkin to, bii eera to ko sinu suga, nnkan kan wa lodo ikun re to n ba a ninu je.
Nnkan naa ni iwa ibaje to wa laarin opo oloori ijo Olorun.
Adeboye fi ehonu re han lori eyi nigba ti won n se idanileko pataki kan lati sami ayeye ojobii naa.
Nibi ipade naa to waye ni ilu Eko, nibi t iyawo Daddy GO, Pasito Foluke Adeboye, ti soju baale re, o salaye pe loooto, iwa wobia wonbiliki wa ni ijoba Naijiria, sugbon eyi to wa laarin awon olori ijo gan-an ju wobia lo.
O war o gbogbo eniyan ki won pada si odo Olorun, ki won se maa se bi Bibeli se fe.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…