Home ỌRỌ̀-AJÉ Àgbà ìsòwò tí kò lẹ́lẹ́gbẹ́, Sai Dangote, Sai Baba!
ỌRỌ̀-AJÉ - February 18, 2017

Àgbà ìsòwò tí kò lẹ́lẹ́gbẹ́, Sai Dangote, Sai Baba!

Omo ti yoo ba je Asamu, lati kekere lo ti n j’enu samusamu. Gege bee ni ti onile ise nla ti a mo si Alhaji Aliki Dangote je.
Idi ni pe lati igba to ti wa nikekere, to n gbe pelu awon obi re ni ilu Kano, lo ti maa n fi apere han pe ise okowo ni kadara oun yan.
Nigba naa, onise okowo to ri jaje ni baba re je.
Ti baba naa ba wa fun Aliko ati awon omo re yoku lowo, dipo ti Aliko yoo fin a owo naa ni iankuna, yoo lo ra suuti ati awon nnkan peepeepe miiran, ti yoo sit un won ta.
Oro tie kuro ni owo ti omode ba koko ri, eko ati akara lo fi maa n je.
Kerekere, Aliko Dangote ma di eni to n ni soobu nla tie, to si fi di eni to da ile ise sile kaakiri orile ede Afirika.
O fee ma si orileede eniyan dudu ti ile ise Aliko ko si.
Bi o se n ni owo kun owo, to fi di eni to lowo ju ni Afirika, lo si n gba opo eniyan sise.
Loooto, logbologbo to n fi oro aje Naijiria bayii ko yo eni kankan sile.
Bi o se n ba olowo finra naa lo n ba talaka po o.
Koda, awon isowo agba bii Alhaji Aliko Dangote ati Femi Otedola naa ti fara gba nibi kinni ohun, tori owo ti won ni bayii ti dinku die si ibi towa tele.
Sugbon ni ti Dangote, o da IROYIN OWURO loju to ada pe owo re yoo tubo ya mira laipe yii.
Idi ni pe ise tii fee pari lori ile ise fopofopo, iyen refinery, to n ko lowo ni Ipinle Eko.
Ti ile ise yii ba pari, o je pe odo Dangote ni opo omo Naijiria yoo ti maa ra epo betiro ati awon ohun amulo miiran to far ape e .
Owo ojumo ti ko kere ni eyi a je fun Dangote, paapaa nigba to je pe ile okeere ni Naijiria ti n ko opo epo to n lo wole.
Adura wa nip e ki Olorun tubo maa lora emi re.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…